Download Iwo Ni Mp3 by Omolola Oguntoye
Hereโs a song by the Nigerian Christian music minister and fast-rising praise worship leader โOmolola Oguntoyeโ whose song has been a blessing to live. The song is titled โIwo Niโ.
Get Audio Mp3, Stream, Share, and be blessed.
Accoording the the book of 1sam 2vs19, the bible says that By strength shall no man prevail, this new song IWO NI is dedicated to our Lord jesus christ, Almighty God, the source of our strength, our shield and our comforter.
Lyrics: Iwo Ni by Omolola Oguntoye
[Intro]
O, O, O Iwo ni
Iwo ni imole mi
Iwo ni imole mi
Iwo ni atona mi
Iwo ni olutunu mi
O,O,O Iwo ni
Eyin ni atona mi
Eyin ni imole mi
Eyin ni olutunu mi
[Chorus]
Iwo ni imole mi nigba to okunkun su
Iwo ni agbara mi nigba ti o si oluranlowo
Iwo ni imole mi, Iwo ni imole mi (2ce).
[Chorus]
Iwo ni imole mi nigba to okunkun su
Iwo ni agbara mi nigba ti o si oluranlowo
Iwo ni imole mi, Iwo ni imole mi
[Verse]
Iwo ni adurotini gbagba lojo isoro
Oba ti o dojutimi ti o fimisile fun yaje
Oba to to gbekele e e e, Iwo ni
Iwo ni olorun mi Iwo ni
[Chorus]
Iwo ni imole mi nigba to okunkun su
Iwo ni agbara mi nigba ti o si oluranlowo
Iwo ni imole mi, Iwo ni imole mi
Bridge-(Call and response)
Olutunu mi, Iwo ni
My help, my shield
Adurotini
Olugbeja omo orukan
Olorun mi
Oba ti o ko mi sile
Oba ti o fimisile
Olorun mi
Aseda mi
Oba to to gbojule
Oba ti o doju timi rara
Nigba ojo nigba erun
e, e, e eyin ni
eyin ni olorun mi
My comforter, my shield
A to gbojule
Ato foro lo