Download Olorun Oba Imole Mp3 by Bisi Manuel
A soul-lifting song from the African Christian/Gospel worshipper, minister, and song writer โBisi Manuelโ, as He calls this song โOlorun Oba Imoleโ. This song is sure to bless your heart and uplift your spirit.
Download Audio Mp3, Stream, Share, and be blessed
DOWNLOAD MORE BISI MANUEL SONGS HERE
You May Also Like: ๐๐ฝ
Lyrics: Olorun Oba Imole by Bisi Manuel
Olorun Oba Imole
Oba aiye raiye e,
Ologo didan julo,
Waju eniti,
Kekere ninu ese,
Ki yio le sunmo O,
To nfi ife pee lese
Lati r’ogo Re.
2.Awon ti o fe lo npe,
Awon to pe loyan a
Awon to yan lo se l’ogo,
Laiye okunkun,
Aiye nko ipe na,
Nwon rin sinu okunkun,
Lai re ronupiwada,
Labe iparun.
3.Ire t’ale logba Eden,
Ronupiwada a,
Wa si ibugbe Imole,
Ibugbe Ife,
Nibiti Jesu njoba,
Niwaju ite Baba,
Elese ronupiwada,
Ma ko ipe na. Amin
You May Also Like: ๐๐ฝ