Download Iwo Lolorun Mp3 by Dorcas Moore
Hereโs a song by theย Nigerian Christian musicย minister and fast-rising praise worship leader โBona Goldโ whose song has been a blessing to live. The song is titled โIwo Lolorunโ.
Get Audio Mp3, Stream, Share, and be blessed.
Lyrics: Iwo Lolorun by Bona Gold
Iwo Lolorun to GA ju aye loโฆ
Iwo lolorun to GA ju eniyan lo
Se biwo Lolorun yii o, teni Kan Kan o le baaa..
Se biwo lolorun yiii o, teni Kan Kan o toโฆIWO LOLORUN to Lagbara ju gbogbo eniyan loโฆ
Iwo lolorun ta won Ogun Orun mbooo..
Sebi Iwo lolorun yi o, to Lagbara giga giga, sebi Iwo lolorun yi o te da Kan o le to, Lai laiChr: Iwo lolorun yi GA ju aye lo
Iwo lolorun to GA ju eniyan lo
Se b’iwo lolorun yiii o, teni Kan Kan o le baaa
Se b’iwo lolorun yii o, teni Kan Kan o toโฆVerse1: Awamaridi nii o o, aditu loruko reโฆ
Gbogbo ologbon aye wa Di re o, won o ri Di Agbara re..
Yeeee, Okun ati Osa nhooo, won o ridi Agbara ra re.
Eja Inu ibi, sa pe juwe ise owo re
Bi afefe ti n fe, O sa pejuwe ise re..
Eniyan atewe be, sa pejuwe ise owo reโฆ.
Iwo nii o(back to Chorus)
Sax medleyโฆโฆ Modulation
(back 2 chorus)Iwo lolorun to GA ju aye lo
“IWO nii ooo”
” Baba miii”
Iwo lolorun to GA ju eniyan lo
“seb’iwo loga ju eniyan lo Alagbara giga”
Se bi’wo lolorun yi o
“IWO ni, Iwo ni o”
Teni Kan Kan o le baaa
“There’s no one that can compare with your name Lord”
Sebi Iwo lolorun yi o o “Arugbo Ojo baba mii
Teni Kan Kan o toโฆ
” You are great “
(chorus)Iwo lolorun to GA ju aye lo
” there’s no one that can share your glory “
” You are the king of kings”
“You are the Lord of Lord’s”
Iwo lolorun to GA ju eniyan lo
“the ancient of days, the rock of ages”
“you are the mighty man in battle “
Sebi Iwo lolorun yi o te ni Kan tan o le baaa
“I bless your name Lord”
“I worship you Lord, I refrerence your name”
Se biwo Lolorun yii o, teni Kan Kan o to..
“there’s none like you, there’s none like youโฆ
” We say Holy are you Lord”
Iwo lolorun to GA ju aye lo
” Lord you are Holy, you are the Oba Arugbo Ojo”
“Oba mi adagba ma te PA, Oba mi adagba ma lo gilaaasi”
Iwo lolorun to GA ju eniyan lo
“” Eru jeje to mi gbo kiji kiji”
“I bless your name Jesus”
Se biwo Lolorun yii o, teni Kan Kan o le baaa
“I worship you Lord” I bless you Lord”
Se biwo Lolorun yii o, teni Kan Kan o toโฆCall: Eleti gba ro ye Eda o
Eleti Kara bi ajere
Res: seb’iwo lolorun yiii o, teni Kan Kan o to
Call: Oba mi okan soso ajanaku o, to mi gbo kiji kiji yeee
Res: seb’iwo lolorun yiii o, teni Kan Kan o to
Call : Oba mi to loyun Ara re, to gbebi Ara re, to tun wa so ra re loruko, laye lorun ko so’ba bi re o..
Res: seb’iwo lolorun yiii o, teni Kan Kan o to
Till fadesโฆ.
Social media details:ย ย Facebook: Bona Gold
Instagram: bonagold1
Youtube: Bona Gold