Gospel Music Nigerian Gospel Songs JoyNoel – Ni Igbagbo

JoyNoel – Ni Igbagbo

Ni Igbagbo
Ni Igbagbo

Here’s a song by the Nigerian Christian music minister and fast-rising praise worship leader , whose song has been a blessing to lives. The song is titled “Ni Igbagbo”.

Ni igbagbo is a yoruba themed song, with plethora of rhythmic infusion describing the faithfulness of God. It is a praise song that leads you to proclaim the everlasting faithfulness of God. When you speak out your needs and expectations in faith confession, GOD HEARS. He will not disappoint.

Get Audio Mp3, Share, Stream, and be blessed.

DOWNLOAD HERE

Joy is an ordained minister, singer, and writer with a passion for inspiring others. Through her voice and words, she uplifts hearts and minds, reminding us that no matter the challenge, ‘There is always a better tomorrow ahead.'”

Lyrics: No One Like You by Mayoung GWM

Chorus 1
Sa ni’gbagbọ ninu Ọlọrun (Have faith in God)
Sa ni’gbagbọ ninu Ọlọrun (Have faith in God)
Sa ni’gbagbọ ninu Ọlọrun (Have faith in God)
Ko ma idoju timi ri (He has never put me to shame)
Sa ni’gbagbọ ninu Ọlọrun
Sa ni’gbagbọ ninu Ọlọrun
Sa ni’gbagbọ ninu Ọlọrun
Ko ma idoju timi ri


Verse 1
Mo ti gba iyanu (I have received a miracle)
Mo ni Ọla (I have wealth)
Mo ni ayọ aiyeraiye (I have everlasting joy)
Ibukun Oluwa pọ o (God’s blessings abound)


Chorus 1
Sa ni’gbagbọ ninu Ọlọrun
Sa ni’gbagbọ ninu Ọlọrun
Sa ni’gbagbọ ninu Ọlọrun
Ko ma idoju timi ri
Sa ni’gbagbọ ninu Ọlọrun
Sa ni’gbagbọ ninu Ọlọrun
Sa ni’gbagbọ ninu Ọlọrun
Ko ma idoju timi ri


Verse 2
Fi aiye rẹ fun Ọlọrun (Give your life to God)
Fi soro rẹ fun Ọlọrun (Give your challenge to God)
Ni gboya ninu Ọlọrun (Have confidence in God)
Ọlọrun aiyeraiye (Everlasting God)
Yio fi ifẹ rẹ bo ọ (He will cover you with His love)
Ko ni jẹ ki oju ko ti ọ (He will not put you to shame)
Ko si nkan ti ko le se (There is nothing he cannot do)
Ole se ohunkohun (He can do all things)
Isẹrẹ iyanu ni (His work is miraculous)
Isẹrẹ iyanu ni (His work is miraculous)
Isẹrẹ iyanu ni (His work is miraculous)
Ko ni jẹ ki oju ko ti ọ (He will not allow you to be put to shame)


Chorus 2
Isẹrẹ iyanu ni (His work is miraculous)
Isẹrẹ iyanu ni (His work is miraculous)
Isẹrẹ iyanu ni (His work is miraculous)
Ko ni jẹ ki oju ko ti ọ (He will not allow you to be put to shame)
Isẹrẹ iyanu ni
Isẹrẹ iyanu ni
Isẹrẹ iyanu ni
Ko ni jẹ ki oju ti ọ


Chorus 1
Sa ni’gbagbọ ninu Ọlọrun
Sa ni’gbagbọ ninu Ọlọrun
Sa ni’gbagbọ ninu Ọlọrun
Ko ma idoju timi ri
Sa ni’gbagbọ ninu Ọlọrun
Sa ni’gbagbọ ninu Ọlọrun
Sa ni’gbagbọ ninu Ọlọrun
Ko ma idoju timi ri


Chorus 2
Isẹrẹ iyanu ni
Isẹrẹ iyanu ni
Isẹrẹ iyanu ni
Ko ni jẹ ki oju ti ọ
Isẹrẹ iyanu ni
Isẹrẹ iyanu ni
Isẹrẹ iyanu ni
Ko ni jẹ ki oju ti ọ
Isẹrẹ iyanu ni
Isẹrẹ iyanu ni
Isẹrẹ iyanu ni
Ko ni jẹ ki oju ti ọ

Comment below with your feedback and thoughts on this post.