Gospel Music Nigerian Gospel Songs Logan Ti Ode – Tope Alabi & TY Bello (Mp3 + Lyrics)

Logan Ti Ode – Tope Alabi & TY Bello (Mp3 + Lyrics)

Download Logan Ti Ode MP3 by

The prolific Nigerian praise worship gospel singer and songstress who has won lots of great award in the Christian music industry โ€œTope Alabiโ€ comes through with a powerful tune, as it always comes in the Yoruba dialect. This song is titled โ€œAnLogan Ti Odegeliโ€œ.

Get Audio Mp3, Stream, Share, and stay blessed alwaysโ€ฆ

DOWNLOAD MP3 HERE

Video: Logan Ti Ode by

Logan Ti Ode Lyrics by

Emi mo’un ojumi tiri
Mo mo’un etimi ti gbo
Mo mo’un ojumi tiri
Mo mo’un etimi ti gbo
Logan to gbo iro ayo re o
Mo mo’un aye ma tiwi
Mo mo’un eniyan ma tiso
Won ti pe wa ni agan ri
Bo ya won ti pe o lo’loshi ri
Sugbon logan to de o
Olugbala l’aye mi leto
Sugbon logan to de yi o
Olugbala l’aye e leto
Aye to ti daru tele tele oo
Logan ti o de
Oro ti eniyan ti n fi alufani re
Logan ti o de
Oro ti ko dara ti a ti so si o
Logan ti o de
Oruko ti kin se ti e ta ti pe o
Logan ti o de
Ani logan ti o de o
Olugbala, aye e leto
Logan ti o de o
Olugbala, aye e leto
Logan ti jesu de
Olugbala, l’aye e leto
Ko si oruko ti aye o le peni
Won a ma peni l’agan lona gbogbo
Bo ba lowo l’owo, agan ni
Bo ba bimo o, agan ni
Bo ba t’egbe ko d’agba, agan loje
Sugbon logan ti o de
Sope logan ti o deโ€ฆ

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here