Gospel Music Nigerian Gospel Songs EBE – Sola Allyson (Mp3, Video, and Lyrics)

EBE – Sola Allyson (Mp3, Video, and Lyrics)

Download EBE MP3 by

Here an amazing song from the Nigerian soul, folk and gospel singer, and song-writer, who came into limelight with the hit album Eji Owuro. Sola Allyson-Obaniyi who is popularly known as Shola Allyson comes through with this song titled โ€œEBEโ€œ.

Get Audio Mp3, Stream, Share, and stay blessed alwaysโ€ฆ

DOWNLOAD MP3 HERE

Official Video for “EBE” by

EBE Lyrics by

Lord, I’ve come to seek Your face
Let Your grace and Your mercy come upon me, Lord
Oh Lord, I call upon Your name
Let the rain of Your mercy pour upon me, Lord
Oluwa, mo wa sibi ite
Je ki oore ofe ati aanu Re, Oluwa
Ko ba le mi lori
Oluwa, mo ke p’Oruko Re
Je ki ojo aanu Re o, Baba
Ko ro s’ori iseda mi
Baba ooooo, eyi l’ebe o
Baba Alaanu, Olugbebe, gbo ebe mi Oluwa o (Baba ooooo, eyi l’ebe o)
Aye mi ko bu ola fun O ni mo n beere
(Baba ooooo, eyi l’ebe o) Ona mi to wo,
Ko di tito ninu ife Re Oluwa o, Eyi ni ebe mi o
Gba mi lowo asise, Oluwa o (Baba ooooo,
Eyi l’ebe o) Gba mi lowo ogun t’apa obi mi o ka,
Gba mi lowo ogun irandiran,
Oluwa gba mi oo Baba, Iwo ni mo gbeke mi le o, Eni to ni emi mi
Oluwa too ba to mu awon afoju san, (Baba ooooo,
Eyi l’ebe o) Oba to ji oku omo Jairu dide, Oku Lasaru,
Ojo merin, o ti n ra, o ti n run, Iwo lo ji i dide o, Oluwa saanu mi
Jesu, omo Dafidi, gbo adua mi,
Oluwa (Baba ooooo, eyi l’ebe o) Baba oooo,
Oore ofe Re ni mo beere, aye o see gbe laisi oore ofe Re, Oluwa o
Mo fi oore ofe Re ra aye gbe, Oluwa (Baba ooooo, eyi l’ebe o)
Atupa imo mi ko ma se ku lailai (Baba ooooo,
Eyi l’ebe o) Iwo ni opo fitila to n tan fun emi mi Oluwa ooo
Oro Re wipe bi mo beere, ma a ri gba,
Mo n beere ki n ri gba (Baba ooooo, eyi l’ebe o) Bi mo ba kan ‘lekun,
Ilekun a si, ilekun ko si, a si ti ko wipe,
Bi mo ba wa kiri, ma a ri,
Mo n wa kiri, ki n ri o, ki n ni ere to po, Oluwa o
Baba Alaanu ooo (Baba ooooo,
Eyi l’ebe o) Ohun gbogbo to wa ninu iseda n gbimo aanu
Si ayanmo mi, won n sise iranwo lori ayanmo mi, Oluwa o
Ilekun si le, ilekun aanu si le, Oluwa (Baba ooooo,
Eyi l’ebe o) Aanu ro sori mi, o ro sori mi bee, Olugbebe gbo ebe mi o
Oh Lord I’ve come to seek Your face
Let Your grace and Your mercy come upon me, Lord
Oh Lord, I call upon Your name
Let the rain of Your mercy pour upon me, Lord
Oluwa, mo wa sibi ite
Je ki aanu ati oore ofe Re
Ko ba le mi lori
Oluwa, mo ke p’Oruko Re
Je ki ojo aanu Re
Ko ro s’ori iseda mi
Baba ooooo, eyi l’ebe o

LEAVE A REPLY

Please enter your comment!
Please enter your name here