Download Mimo L’Oluwa MP3 by Tope Alabi
The prolific Nigerian praise worship gospel singer and songstress who has won lots of great award in the Christian music industry “Tope Alabi” comes through with a powerful tune, as it always comes in the Yoruba dialect. This song is titled “Mimo L’Oluwa“.
Get Audio Mp3, Stream, Share, and stay blessed always…
Mimo L’Oluwa Lyrics by Tope Alabi
Mimo l’Oluwa o (mimo)
Angeli nwo mike o (mimo)
Awon orun nwo mike (mimo)
Egbagbeje irawo o (mimo)
Mimo l’Oluwa (mimo)
Angeli nwo mike o (mimo)
Awon orun nwo mike (mimo)
Egbagbeje irawo o (mimo)
Agbagba merinlelogun (mimo)
N’origun merin aye o (mimo)
Ati oke, ati ile (mimo)
Seri nwo ke o (mimo)
Tani yo gori oke Oluwa (mimo)
Tabi tani yo duro ni’be o (mimo)
Eni ti o ni owo mimo (mimo)
Ati aya funfun (mimo)
Mimo l’Oluwa (mimo)
Mimo o mimo (mimo)
Mimo o mimo o mimo (mimo)
Mimo o funfun nene ni
Kabiyesi Eledumare Oba mimo (mimo)
Oba la gbogbo aye ete riba fun oba ti oda gbogbo adarihunhun
Oba ti oni emi inu eniyan pata
Oni kokoro aye l’ lowo
Adagodo emi gbogbo eniyan
Olu kogan orun ajosi edumare
Ibinigbi awuwo bi atele
Opa tiri kole o ko orun
Minimi ojo ti jeki ara odehin…